Mohammed Salah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mohammed Salah

Mohammed Salah je Agbààbọlu lokunrin ti orilẹ ede Egipiti,[1] bakan naa ni osi je agbaboolu fun Iko Liverpool ti Liigi Ile-Geesi ti a mosi Premier League.[2] Won bii ni Ojo Karundinlogun, Osu Kefa, Odun 1992.[3] Oje ogbontarigi agbaboolu iwaju fun iko Liverpool, bakan naa ni captain fun Iko Orilede Egipti. Oje Agbaboolu ti a kole foworoseyin ni ile Afrika ati ni agbaye lapapo

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.cnn.com/2018/06/24/football/mo-salah-egypt-world-cup-russia-2018-spt-intl/index.html
  2. https://www.thesun.co.uk/sport/football/16966962/mo-salah-transfer-liverpool-man-utd/
  3. https://www.egypttoday.com/Article/4/52004/New-book-Mohamed-Salah-%E2%80%9CThe-Story-of-a-Hero%E2%80%9D