Moji Makanjuola
Ìrísí
Moji Makanjuola jẹ́ ogbontarigi oniroyin àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni Nàìjíríà.[1][2] Òun ni adarí tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ àwọn oniroyin obìnrin ni Nàìjíríà (NAWOJ).[3][4] Wọ́n bíi Moji sì ilẹ̀ Kwara, ó sì jẹ ìkan laarin awọn oniroyin tí ó dá sí ìgbà sókè ìròyìn ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà pàápàá jù lọ ní eka ìròyìn nípa ìlera.[5] Òun ni olumoran media fún àwọn obìnrin UN.[6] Ó si ṣẹ́ pelu Nigeria Television Authority (NTA) kí ó tó di adarí ni èka ìlera. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ni Center for Disease Control, ní USA.[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Moji Makanjuola’s day of joy". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 30 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "New Telegraph – Service chiefs, eight governors, others make National Honours list". Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 30 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ http://allafrica.com/stories/200702260564.html
- ↑ "Moji makanjuola: I never lied for government - The Sun News". The Sun News. Retrieved 30 September 2014.
- ↑ "First Lady pledges increased advocacy for women’s health". Archived from the original on 30 September 2014. Retrieved 30 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Towards restoring peace in Northern Nigeria through women". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Retrieved 30 September 2014.
- ↑ "The Challenge Judges - The African Story Challenge". Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 30 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)