Moky Makura
Ìrísí
Moky Makura jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọ̀ròyìn, òṣèrébìnrin àti oníṣòwòbìnrin tó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí Africa No Filter, [1] èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí àyípadà tó ń bá ilè Africa látàri ẹ̀rọ ayélujára.
Ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Makura ní Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìdílé Akisemoyin, èyí tó jẹ́ ìdílé Oba ní Nàìjíríà. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ètò ìṣèlú, ètò ọ̀rọ̀-ajé àti ìmọ̀ òfin, láti Yunifásitì ti Buckingham. Ní ọdún 1998, ó kó lọ sí South Africa,[2][3] àti ní ọdún 1999, ó bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ tirẹ̀.[4] Òun ni olùṣàkóso kejì fún Communications Africa ní Bill and Melinda Gates Foundation.[5] Láti ọdún 2017, ó jẹ́ aṣojú ẹgbẹ́ náà ní South Africa. [6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Mogoatlhe, Lerato (18 August 2020). "Moky Makura Wants to Change the Way the World Sees Africa by Empowering Its Storytellers". Global Citizen. https://www.globalcitizen.org/en/content/moky-makura-african-stories/.
- ↑ "Moky Makura". Africa No Filter.
- ↑ "Moky Makura". TVSA - The South African TV Authority.
- ↑ SAinfo reporter (18 February 2009). "Meet Africa’s greatest entrepreneurs". Brand South Africa. https://www.brandsouthafrica.com/investments-immigration/africa-gateway/greatestentrepreneurs.
- ↑ "Meet Africa’s greatest entrepreneurs". https://www.brandsouthafrica.com/investments-immigration/africa-gateway/greatestentrepreneurs.
- ↑ Empty citation (help)