Jump to content

Molière

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jean-Baptiste Poquelin
Portrait of Molière by Nicolas Mignard
Pen nameMolière
Iṣẹ́Playwright
Ọmọ orílẹ̀-èdèFrench
Ìgbà1645-1673
GenreComedy
Notable worksTartuffe; The Misanthrope; The Learned Women; The School for Wives; L'Avare
SpouseArmande Béjart
PartnerMadeleine Béjart

Jean-Baptiste Poquelin, to gbajumo bi oruko ori itage re Molière, (ìpè Faransé: ​[mo.ljɛːʁ]; baptised January 15, 1622 – February 17, 1673) je osere ati ako ere ara Fransi to je gbigba bi ikan ninu awon elere alawada ninla julo ninu isemookomooka.[1] Ninu awon iwe re ni Le Misanthrope (The Misanthrope), L'École des femmes (The School for Wives), Tartuffe ou L'Imposteur, (Tartuffe or the Hypocrite), L'Avare (The Miser), Le Malade imaginaire (The Imaginary Invalid), ati Le Bourgeois Gentilhomme (The Bourgeois Gentleman).


  1. Hartnoll, p. 554. "Author of some of the finest comedies in the history of the theater." and Roy, p. 756. "...one of the theatre's greatest comic artists."