Jump to content

Moncef Marzouki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Moncef Marzouki
المنصف المرزوقي‎
President of Tunisia
ad interim[1]
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
13 December 2011
Alákóso ÀgbàBeji Caid el Sebsi
Hamadi Jebali (Designate)
AsíwájúFouad Mebazaa (Acting)
Leader of the Congress for the Republic
In office
24 July 2001 – 13 December 2011
DeputyAbderraouf Ayadi
AsíwájúPosition established
Arọ́pòAbderraouf Ayadi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Keje 1945 (1945-07-07) (ọmọ ọdún 78)
Grombalia, Tunisia
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCongress for the Republic
Alma materUniversity of Strasbourg
WebsiteOfficial website

Moncef Marzouki (Lárúbáwá: المنصف المرزوقي‎ (al-Munṣif al-Marzūqī); ojoibi 7 July 1945) je alakitiyan eto omoniyan oniwosan ati oloselu ara Tunisia. Ni ojo 12 osu December odun 2011 o je didiboyan bi Aare ile Tunisa igbadie latowo Ile Igbimo Abagbepo. Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Moncef Marzouki jẹ koko-ọrọ ti iwe-aṣẹ imuni ilu okeere fun eewu aabo ilu.
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named WP_president