Jump to content

Monday Obolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Monday Obolo je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà osìn gẹ́gẹ́ bí Aṣojú Ìpínlẹ̀ tó ń ṣoju ẹkùn ìdìbò Gusu Ijaw II ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Bayelsa . [1] [2]