Jump to content

Moniepoint Microfinance Bank

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Moniepoint Inc.
Founder(s)Tosin Eniolorunda
Key people
Industry
  • Business Banking
  • Financial Technology
Products

Moniepoint Inc, (tí a mọ tẹ́lẹ̀ sí TeamApt Inc)[1][2] jẹ́ ilé-iṣẹ fintech tí Tosin Eniolorunda jẹ́ Oludasilẹ iléṣẹ náà ní ọdún 2015 tí o dálé lórí wí wá ọ̀nàbáyọ sí ètò ìsúnná.

Moniepoint ti wà lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó ti lórúkọ lórí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lẹ́yìn tí wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún 2022 láti ọwọ́ CB Insights.[3][4] Moniepoint tún gbàmì ẹ̀yẹ Financial Inclusion Award[5] láti ọwọ́ ilé-ìfowópamọ́ gbogboogbò ti ilẹ̀ Nàìjíríà níbi àpérò àgbááyé ti Financial Inclusion ní ọdún 2022.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Muktar, Oladunmade. "TeamApt sheds its name, rebrands as Moniepoint". TechCabal. TechCabal. Retrieved 13 January 2023. 
  2. Oladunmade, Muktar (2023-01-21). "Moniepoint: Rebranding a Fintech Giant". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-17. 
  3. Investors, King. "FINTECHOPay, Paga, Others Makes CB Insights List of Promising Fintech Startups 2022". Investors King. Investors King. Retrieved 5 October 2022. 
  4. Oluwole, Victor (2022-10-05). "6 most promising African fintech startups as per CB Insights 2022 list". Business Insider Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-09. 
  5. Olayinka, Ajayi. "CBN award institutions, individuals advancing financial inclusion in Nigeria". https://www.vanguardngr.com/2022/11/cbn-award-institutions-individuals-advancing-financial-inclusion-in-nigeria/.