Moscow International Business Center
Moscow International Business Center (Rọ́síà: Московский Международный Деловой Центр; ММДЦ) wọ́n tún ń pèé ní Moscow City[1][2] (Rọ́síà: Москва-Сити) jẹ́ agbèègbè ìṣòwò ní àárín Moscow, Russia.
Àwọn àtúnṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Official website". Eng.citynext.ru. Retrieved 25 September 2010.
- ↑ "Construction World: Integrated Body For Urban Design Policy And Development Of Moscow". Stroi.ru. Retrieved 25 September 2010.