Moses Ọláìyá Adéjùmọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Moses Olaiya
Ìbí Moses Olaiya Adejumo
Àwọn orúkọ míràn Baba Sala
Àwọn ọmọ Emmanuel Adejumo[1]
Oyindamola Adejumo [2]

Moses Ọláìyá Adéjùmọ̀ (ojo ibi 1936) je gbaju gbaja osere ori amohun-maworan ati oni sinima omo ile Naijiria Ohun ni opo eniyan mo si "Baba Sala". O je Alawada kerikeri elere ori itage Yoruba.

Moses Adejumo je omo ilu Ijesha ni ipinle Osun.Baba Sala ni a gba pe o je Oludasile awada (Comedy) ninu ere Sinima ile Yoruba, gege bi o se ba awon ogbon-tagi osere ori itage Yoruba miran bii: Hubert Ogunde, Kola Ogunmola, Oyin Adejobi ati Duro Ladipo bi o se je wipe awon ni won pile ti won si gbe ere Sinima ori itage Yoruba gun oke agba doni, bakan naa ni o je oun paapaa mu idagba-soke ba Sinima Yoruba lapapo ni ilana tire naa.

Awon akojopo ere re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Orun Mooru (1982)
 • Aare Agbaye (1983)
 • Mosebolatan (1985)
 • Obee Gbona (1989)
 • Diamond (1990 Home video )
 • Agba Man (1992, Home Video)
 • Return Match (1993, Home Video)
 • Ana Gomina (1996, home video, )
 • Tokunbo (1985, TV)


Itoka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Abodunrin, Akintayo. "Feast of drama for the dramatist". 234NEXT.com. Retrieved 2009-09-19. 
 2. "Gospel". African Gospel Music Center. Retrieved 2009-09-19. 


External links[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]