Moses Da Rocha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Moses Da Rocha, èyí tí a bí ní oṣù kìn-ín-ní ọdún 1875, tí ó sì kú ní oṣù karùn-ún ọdún 1942, jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó, akọ̀ròyìn, àti olóṣèlú. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn onímọ̀ ìṣẹgun òyìnbó bí i Africanus Horton, Orisadipe Obasa, àti John K. Randle tí wọ́n mú iṣé ìṣègùn mọ́ òṣèlú. Ní ọdún 1923, nígbà tí ó kù dẹ̀dẹ̀ kí ìdìbò ìgbìmọ̀ lẹjisilétíìfù bẹ̀rẹ̀, ó dá egbẹ́ "the Union of Young Nigerians" sílẹ̀.


Ìgbé ayé àti èkọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]