Moses Edet Essien
Ìrísí
Moses Essien jẹ́ olóṣèlú àti aṣofin ní orílè-èdè Nàìjíríà. O n ṣe aṣoju àgbègbè Ibiono Ibom ni Ile-igbimọ aṣofin Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom labẹ ẹgbẹ tí Young Progressive Party (YPP). [1] [2] [3] [4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://dailypost.ng/2024/02/04/ypp-wins-reps-state-assembly-rerun-elections-in-akwa-ibom/
- ↑ https://independent.ng/aibom-lawmaker-initiates-free-medical-outreach-in-ibiono-ibom/
- ↑ https://businessday.ng/news/article/akwa-ibom-lawmaker-seeks-provision-of-roads-in-farming-communities-to-boost-food-production/
- ↑ https://leadership.ng/lawmaker-seeks-fgs-intervention-as-flood-worsens-calabar-itu-highway/