Moving Picture Experts Group

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Moving Picture Experts Group (MPEG) je egbe osise awon oloye ti o je didasile latowo ISO lati sakojopo awon opagun fun igepapo olohun ati filmu ati irankiri won.[1] O je didasile ni 1988, wo se ipade akoko won ni May 1988 ni Ottawa, Canada.[2][3][4]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. John Watkinson, The MPEG Handbook, p.1
  2. "About MPEG". chiariglione.org. Retrieved 2009-12-13. 
  3. "MPEG Meetings". chiariglione.org. Archived from the original on 2010-02-10. Retrieved 2009-12-13. 
  4. chiariglione.org (2009-09-06). "Riding the Media Bits, The Faultline". Archived from the original on 2011-01-22. Retrieved 2010-02-09.