Mowo, Badagry

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mowo
Town
Mowo is located in Nigeria
Mowo
Mowo
Coordinates: 7°11′N 5°35′E / 7.183°N 5.583°E / 7.183; 5.583Coordinates: 7°11′N 5°35′E / 7.183°N 5.583°E / 7.183; 5.583
Country Nigeria
State[[Lagos[1]State]]
Time zoneUTC+1 (WAT)

Mowó jẹ́ ìlú kan ní Àgbádárígí, Ìpínlẹ̀ Èkó , ní apá Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Ìlú náà kò jìnà púpọ̀ sí agbègbè ìloro ibodè Sẹ̀mẹ̀. Kò ju ìwọ̀n kìlómítà diẹ̀ lè. Àwọn tí wọ́n tó ìdá 78,897, àwọn olùgbé tí ó ń gbé níbẹ̀ lọ. Púpọ̀ nínú àwọn olùgbé ìlú yí ni wọ́n jẹ́ olùṣòwò àti olùtajà tí wọ́n sì ma ń lè láti ra àwọn Ọjà títà wọn ní Sẹ̀mẹ̀. Agbọ́ wípé àwọn ilé tí wọ́n tó ìdá ọgọ́fà (600) tí ó wà ní orí ilẹ̀ tí ó tó àádóje (65) hẹ́kítà ni ilé-iṣẹ́ àjọ Ọlọ́pàá ilẹ̀ Nàìjíríà bì wo lulẹ̀ láti lè kọ́ ilégbèé àwọn Ọlọ́pàá sí ní ọdún 2013 .[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Driving Directions Map to Mowo Area Mowo Badagry Lagos Nigeria for Biz Id 798835". VConnect™. Retrieved 2019-10-26. 
  2. "Your favorite newspapers and magazines.". PressReader.com. 2019-05-07. Retrieved 2019-10-26.