Jump to content

Mr 2kay

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mr 2Kay
Background information
Orúkọ àbísọAbinye David Jumbo
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kejì 1988 (1988-02-11) (ọmọ ọdún 36)
Port Harcourt, Rivers State Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Rivers State, Nigeria
Irú orinAfro pop music
Occupation(s)Singer, songwriter, performer
Years active2010–present
LabelsBetter Life Entertainment

Abinye David Jumbo tí wọ́n bí ní (February 11, ọdún 1988), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Mr 2Kay, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó fìgbà kan tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú Grafton Entertainment, àmọ́ ó kúrò ní ọdún 2018, láti lọ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀, tó pè ní Better Life Entertainment.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Fighting Their Way to Stardom". AllAfrica. 5 January 2014. http://allafrica.com/stories/201401061760.html. Retrieved 12 August 2015. 
  2. "FACTORY78 – Mr 2Kay Performs Bubugaga Live / Face-off interview". Naija Celebrity. Archived from the original on 10 September 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)