Muhammad Ali Pasha
Ìrísí
Muhammad Ali | |
---|---|
Pasha
| |
Àwòrán Muhammed tí Auguste Couder yà ní ọdún 1840 | |
Reign | 17 May 1805 – 2 March 1848 |
Predecessor | Hurshid Pasha |
Successor | Ibrahim Pasha |
Spouse |
|
Issue | |
| |
Father | Ibrahim Agha |
Mother | Zeinab |
Born | 4 March 1769 Kavala, Sanjak of Kavala, Rumelia Eyalet, Ottoman Empire |
Died | 2 August 1849 Ras el-Tin Palace, Alexandria, Egypt Eyalet, Ottoman Empire | (ọmọ ọdún 80)
Burial | Mosque of Muhammad Ali, Cairo Citadel, Egypt |
Religion | Sunni Islam |
Muhammad Ali Pasha (Lárúbáwá: محمد علي باشا; tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 1769 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1849)[lower-alpha 1] jẹ́ gomina Ottoman[2] àti adarí orílẹ̀ èdè Ìjíptì láàrin ọdún 1805 sí 1848, ọ̀pọ̀ káà mọ́ ara àwọn tí ó kọ́ Íjíptì òde òní. Nígbà tí ìjọba rẹ̀ tàn, ó dárí Egypt, Sudan, Hejaz, Najd, Levant, Cyprus àti apá kan Greece.
Ó jẹ́ olórí ogun nínú àwọn ọmọ ológun Albania tí wọ́n rán láti gba Íjìptì lọ́wọ́ ìjọba France lábẹ́ Napoleon. Lẹ́yìn ìgbà tí Napoleon fi ilé náà sílẹ̀, Muhammad Ali di gómìnà Wāli (gọ́minà) Ìgìptì, ó sì di Pasha.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Khalid Fahmy (1998). All the Pasha's Men: Mehmed Ali, his Army and the Making of Modern Egypt. Cambridge University Press.
- ↑ Özavcı, Hilmi Ozan (2021). Dangerous Gifts: Imperialism, Security, and Civil Wars in the Levant, 1798-1864. Oxford University Press. ISBN 978-0-19-885296-4. https://books.google.com/books?id=Lbo0EAAAQBAJ.
- p. 93: Àdàkọ:Quote
- pp. 97–98: Àdàkọ:Quote
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found