Muhammad Haji Ibrahim Egal
Ìrísí
Mohamed Haji Ibrahim Egal | |
---|---|
محمد حاجي إبراهيم عقال | |
Egal in 1968 | |
2nd President of Somaliland | |
In office May 16, 1993 – May 3, 2002 | |
Vice President | Abdirahman Ahmed Ali Tuur (1993–1995)[1] Abdirahman Aw Ali Farrah (1995–1997)[2] Dahir Riyale Kahin (1997–2002) |
Asíwájú | Abdirahman Ahmed Ali Tuur |
Arọ́pò | Dahir Riyale Kahin |
1st & 4th Prime Minister of the Somali Republic | |
In office July 1, 1960 – July 12, 1960 | |
Ààrẹ | Aden Adde |
Asíwájú | Abdullahi Issa (as the prime minister of the Trust Territory of Somalia) |
Arọ́pò | Abdirashid Ali Shermarke |
In office July 15, 1967 – October 21, 1969 | |
Ààrẹ | Abdirashid Shermarke |
Asíwájú | Abdirizak Haji Hussein |
Arọ́pò | Muhammad Ali Samatar |
Prime Minister of the State of Somaliland | |
In office June 26, 1960 – July 1, 1960 | |
Asíwájú | Office established |
Arọ́pò | Office abolished |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Odweyne, British Somaliland (now Somaliland) | Oṣù Kẹjọ 15, 1928
Aláìsí | May 3, 2002 Pretoria, South Africa | (ọmọ ọdún 73)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United Peoples' Democratic Party Somali Youth League |
(Àwọn) olólùfẹ́ | (1) Edna Adan (2) Asha Saeed Aabi (3) Hawa Ainab (4) Kaltum Haji Dahir |
Alma mater | SOS Sheikh Secondary School |
Signature |
Mohamed Haji Ibrahim Egal (Lárúbáwá: محمد حاجي إبراهيم عقال; August 15, 1928 – May 3, 2002) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Somalia nígbà ayé rẹ̀. Òun ni ó jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Somaliland láàrin ọdún 1993 títí di ìgbà tí ó fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 2002. Ó di ipò mínísítà orílẹ̀ ède rẹ̀ mú fún ọjọ́ mọ́kànlá láti oṣù kẹfà sí oṣù keje ọdun 1960, ó sì tún lọ sáà mìíràn nípò kan náà láàrin ọdún 1967 sí 1969.[3]
Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Egal ní ọdún 1928, ní Odweyne. Ó wá láti ilé Issa Musse ti ìdílé Habar Awal ní ẹ̀ya Isaaq.
Ó ka ìwé prámárí àti sẹ́kọ́ndírí rẹ̀ ní British Somaliland kí ó tó lọ sí United Kingdom. Egal fẹ́ Asha Saeed Abby ní ìyàwó, àwọn méjèèjì sì fẹ́ ọmọkùnrin mẹ́ta àti ọmọbìnrin méjì.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Paquin, Jonathan (July 1, 2010). A Stability-Seeking Power: U.S. Foreign Policy and Secessionist Conflicts. McGill-Queen's Press - MQUP. ISBN 9780773591028. https://books.google.com/books?id=wWv4dHWjDpUC.
- ↑ Bahcheli, Tozun; Bartmann, Barry; Srebrnik, Henry (September 9, 2004). De Facto States: The Quest for Sovereignty. Routledge. ISBN 9781135771218. https://books.google.com/books?id=Gk2QAgAAQBAJ.
- ↑ "Somaliland's Quest for International Recognition and the HBM-SSC Factor". Archived from the original on May 28, 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)