Jump to content

Muhammed Bello

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Muhammadu Bello
محمد بلُّو
Sarkin Musulmi (Commander of the Faithful)

The official seal of Muhammad Bello
Reign 1817–1837
Coronation 22 April 1817
Predecessor Position established
(Usman dan Fodio as Sarkin Musulmi)
Successor Abu Bakr Atiku
Issue
Father Usman dan Fodio
Born 3 November 1781
Died 25 October 1837(1837-10-25) (ọmọ ọdún 55)
Wurno
Religion Islam[1]

Muhammadu Bello jẹ́ Sultan keji ti ìlú Sokoto [2] ó sì jẹ́ ọba láti 1817 Títí di 1837. Ó tún jẹ òlùkọwe tí n ṣe pẹlú ìtàn, ewì, àti àwọn ẹ̀kọ́ ẹ̀sìn Imale . Òun ní ọmọ ati olùrànlọwọ àkọkọ sí Usman dan Fodio, tó jẹ́ Olùdásílẹ̀ Sokoto Caliphate ati Sultan àkọkọ. Ní àkókò ijọba rẹ̀, ó ṣe ìwúrí fún ìtànkálẹ̀ ẹ̀sin Islam ní gbogbo àgbègbè rẹ̀, ó pèsè ẹ̀kọ́ fún àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin, àti ìdásílẹ̀ àwọn ilé-ẹjọ́ Islam. Ó kú ní Oṣù Kẹwàá Ọjọ́ kẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, Ọdun 1837 (25, October 1837), Abu Bakr Atiku sì rọ́pò rẹ̀ àti lẹyìn náà ọmọ rẹ̀, Aliyu Babba .

Àwọ́n ìtọkásí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ISLAMIC CULTURE - AN ENGLISH QUARTERLY: "And say: My Lord! Increase me in knowledge – Qur’an" Archived 2016-03-04 at the Wayback Machine. Vol. LIV No.4 - OCTOBER 1980
  2. Mines of Silver and Gold in the Americas. Aldershot.