Muna (rapper)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Munachi Gail
Miss Nigeria 07 Munachi Abii.jpg
Ọjọ́ìbíMunachi Gail Teresa Abii Nwankwo
Port Harcourt, Rivers State, Nigeria
Iṣẹ́Rap/hip hop recording artiste, songwriter, tv presenter, model
Ìgbà iṣẹ́2005-2015
TitleMost Beautiful Girl in Nigeria (MBGN) 2007

Munachi Gail Teresa Abii Nwankwo jẹ́ olórin, akọrin, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí telefision àti osere ni ìpínlè Nàìjíríà . Ó gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Imo ni Nàìjíríà.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọn bíi sì ilẹ̀ Port Harcourt, ibẹ̀ ni ó sì gbé dàgbà. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Federal Government Girl's College ni Abuloma. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Benson Idahosa University níbi tí ó tí ká International relations and Diplomacy.[2]

Ìṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà ní ọdún 2007 ní ìgbà tí ó sì wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga.[3][4] Óun ló ṣe aṣojú fún Nàìjíríà nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni àgbáyé.[5] Ní ọdún 2009, òun àti ẹni tí ó gbé ìgbà o ròkè ní ọdún 2000 fún ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà, Matilda Kerry jọ ṣíṣe pọ̀ láti sọ̀rọ̀ nípa àrùn jẹjẹrẹ.[6]

Muna celebrating her birthday at Miss World 2007 in China

Munachi je olórin, orúkọ orí ìtàgé rẹ ni Babyrella kí ó tó padà wá yí sì Múná.[7] Ó ti kọ orin fún àwọn olórin bíi J Martins àti Waje. Ó sì má ṣe kópa nínú fíìmù fún àwọn olórin, ó wá nínú fíìmù Ifunaya tí àwọn P Square ṣe.

Ni oṣù kẹfà ọdún 2010, Muna darapọ̀ mọ ilé iṣẹ́ Ayọ̀ Shonaiya RMG company níbi tí ó tí ṣe àwọn orin rẹ̀ bíi The Goddess àti The hustler. [8][9][10][11]

Ní ọdún 2011, Múná darapọ̀ mọ ilé iṣẹ́ Unilever níbi tí ó tí ṣe àwòṣe fún Lux.[12] Ó ṣe atọkun fún eré orí telefision tí Malta Guinness Street Dance Africa.[13]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "Meet the Most Beauriful Girls in Nigeria". buzznigeria.com. Retrieved 6 November 2019. 
 2. Felicia, Onuigbo (August 9, 2018). "30Yrs Old Ex Beauty Queen". gistmania. Retrieved 6 November 2019. 
 3. MBGN website Archived 1 May 2008 at the Wayback Machine.
 4. Vanguard interview with Munachi
 5. "Welcome to Linda Ikeji's Blog". lindaikeji.blogspot.com. Retrieved 2017-08-29. 
 6. Alex, Samade (2010-01-16). "Handing over a relief, Says Munachi Abii". Vanguard. Retrieved 2017-08-29. 
 7. "Modern Ghana - Breaking News, Ghana, Africa, Entertainment" (in en-GB). ModernGhana.com. http://www.modernghana.com/movie/4032/3/munachi-abii-ready-for-music-career.html. 
 8. Linda Ikeji (27 June 2010). "Welcome to Linda Ikeji's Blog: Munachi Abii signs with RMG company". Lindaikeji.blogspot.co.uk. Retrieved 19 April 2014. 
 9. "Munachi Abii Steps Up Music Career". PM NEWS Nigeria. 2010-07-01. Retrieved 2017-08-29. 
 10. "OFFICIAL RELEASE: Muna - I Feel Real (The David Guetta Mix)". NotJustOk. 2010-09-16. Retrieved 2017-08-29. 
 11. "Muna - Killer Queen ft Buckwylla". NotJustOk. 2011-01-09. Retrieved 2017-08-29. 
 12. "BN Exclusive: Munachi as the new Face of LUX Soap – A Sneak Peek of the TV & Print Ads". BellaNaija. 12 May 2011. Retrieved 19 April 2014. 
 13. Johnson, Ayodele (August 2, 2016). "Ex Beauty Queen becomes TV Presenter". Pulse.ng. Retrieved 6 November 2019.