Munezero Aline
Ìrísí
Munezero Aline | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Munezero Aline 1994 Kigali, Rwanda |
Orílẹ̀-èdè | Rwandan |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2015–present |
Munezero Aline (tí wọ́n bí ní ọdún 1994) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi "Milika" nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Gica.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Who is Aline Munezero, one of the most popular filmmakers in Rwanda?". inyarwanda. Retrieved 14 October 2020.
- ↑ "Milka lost her choice between Junior and Rocky". isimbi. Retrieved 14 October 2020.