Murjanatu Musa
No. 11/20 – air warriors | |
---|---|
Àárín, Iwájú | |
Personal information | |
Born | ọjọ́ kaàrún osù kaàrún ọdún 2000 Abuja,Nàìjíríà |
Nationality | Nàìjíríà |
Listed height | 6 ft 2 in (1.88 m) |
Career information | |
Pro playing career | 2018–present |
Career history | |
2018 present | air warriors |
GT2000 | |
ELEPHANT GIRLS | |
Medals
|
Murjanatu Liman Musa tí a bí ní ọjọ́ kaàrún osù kaàrún ọdún 2000 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n orílẹ̀-ède Nàìjíríà tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù lọ́wọ́lọ́wọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Air Warriors ti Nàìjíríà àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà .
Isẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n tí ó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Murjanatu gbábọ́ọ̀lù lọ́wọ́lọ́wọ́ pẹ̀lú ẹgbẹ́ celta zorka ní Spain. Murjanatu ń gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n obìnrin ti Air warriors Nàìjíríà, níbi ìdíje bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n ti obìnrin ti Zenith ní ọdún 2019, ẹgbẹ́ náà jáwé olúborí pẹ̀lú Mountain of Fire Ministries Women’s Basketball ní ìparí, wón dìbò yàán gẹ́gẹ́ bí MVP ti àpapọ̀ eré náà tí ó ní àròpin mẹ́tàdínlógún ojú àmì àti àtúnse márùndínlógún àti ìrànlọ́wọ́ mẹ́ta níbi ìparí eré.
Egbé agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Murjanatu ṣojú Nàìjíríà nínú ìdíje bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n ti 3x3 ti Morocco Africa Games ní ọdún 2019 àti 2019 African Beach Games, Cape-Verde, ẹgbẹ́ náà gba ẹ̀bun wúrà àti Idẹ lẹ́sẹsẹ.
A pe Murjanatu Musa láti ṣojú fún D'Tigress àti láti kópa nínú Tokyo <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/2020_FIBA_Women's_Olympic_Qualifying_Tournaments" rel="mw:ExtLink" title="2020 FIBA Women's Olympic Qualifying Tournaments" class="cx-link" data-linkid="108">2020 FIBA Women's Olympic Qualifying Tournaments</a> ní Belgrade.