Museu Nacional de História Natural de Angola
Ìrísí
Museu Nacional de História Natural de Angola (èdè Yoruba: musíọ́mù àgbà ti Angola fún ìtàn) jẹ́ musíọ́mù kan ní agbègbè Ingombota ní ìlú Luanda, Angola. Òun nìkan ni musíọ́mù ìtàn ni orílẹ̀ èdè Angola.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n dá musíọ́mù náà kalẹ̀ ní ọdun 1938 gẹ́gẹ́ bi Museu de Angola,[1] ó sì kọ́kọ́ wà ní Fortress of São Miguel, ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka nípa ẹranko, àwòrán àti ìtàn. Odún 1956, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń lọ ilé alájà mẹta ní Ingombota.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Directory of museums in Africa. Kegan Paul International. 1 January 1990. p. 28. ISBN 978-0-7103-0378-3. https://books.google.com/books?id=06ohAQAAIAAJ.