Mustapha El Biyaz

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mustapha El-Biyaz
Personal information
OrúkọMustapha El-Biaz
Ọjọ́ ìbí12 Oṣù Kejì 1960 (1960-02-12) (ọmọ ọdún 64)
Ibi ọjọ́ibíTaza, Morocco
Ìga1.73 m (5 ft 8 in)
Playing positionDefender (association football)
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
KAC Marrakech
1987–1988F.C. Penafiel1(0)
National team
1980–1988Morocco national football team42(2)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Mustapha El-Biyaz ni a bini ọjọ kejila, óṣu February ni ọdun 1960 ni Taza jẹ elere bọọlu afẹsẹgba defender ti órilẹ ede Morocco to ti fi ẹhinti. El Biyaz ṣèrè fun Club KAC Marrakech ninu Botola[1][2][3][4][5].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Biyaz kopa ninu Olympic Summer ti ọdun 1984 ati Cup FIFA Àgbayè ti ọdun 1986[6]. Ni ọdun 2006, CAF yan Mustapha gẹgẹbi ọkan lara awọn igba elere bọọlu afẹsẹgba to dara ju ni ilẹ afirica lati adọta ọdun sẹyin[7].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mustapha Statistics and Goals
  2. M. EL Biyaz
  3. Mustapha EL BIYAZ
  4. Mustapha Profile
  5. Morocco - Record International Players
  6. Olympic Games
  7. African Cup Of Nations