Jump to content

Mustapha Khabeeb

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Mustapha Khabeeb je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o ṣiṣẹ gẹgẹbi Senato ti o nsójú agbègbè Jigawa South-West ni ìpínlè Jigawa labẹ ẹgbẹ tí òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). [1] [2]