Muzeum Miniaturowej Sztuki Profesjonalnej Henryk Jan Dominiak ní Tychy
ìbèrè | 16 Oṣù Igbe 2013 |
---|---|
orílè-èdè | Pólàndì |
Ìjoba ìbílè | Tychy, Silesian Voivodeship |
located in time zone | UTC+01:00, UTC+02:00 |
coordinate location | 50°7′1″N 18°58′41″E |
award received | Polish Cultural Merit Order |
official website | http://www.muzeumminiaturowejsztukiprofesjonalnejhenrykjandominiak.eu, https://muzeumminiaturowejsztukiprofesjonalnejhenrykjandominiak.eu/wp/usa/ |
Muzeum Miniaturowej Sztuki Profesjonalnej Henryk Jan Dominiak ní Tychy ó jẹ́ mùsíọ́mù àwọn iṣẹ́-ọnà náà, ó wà ní gúúsù àárín gbùngbùn tí a mò sí ìgbánú àárín, tí ibùjókò rè wà ní ìgboro Żwakowska 8/66, ní ìlú kan Tychy,[1] jẹ́ ìlú ní gúúsù ní Pólándì, ní orílẹ̀-èdè náà Àárín Yúróòpù àti jẹ́ ìkan nínú Ìṣọ̀kan Yúróòpù.[1]
Wọ́n ṣí mùsíọ́mù náà ní ọjọ 16 Oṣu Kẹrin ọdún 2013.[2]
Mùsíọ́mù náà kún fún àkójọpọ̀ àwọn ọ̀hún pàtàkì tí ó ní ṣe pẹ̀lú iṣẹ́ ọnà àti ọ̀hún ìṣẹ̀ǹbáyé àti àwọn ǹkan tí wọ́n fi àmọ̀ ṣe láyé ọjọ́.[1]
Ó ní akojọpọ àwọn kíkún tí oríṣiríṣi kékeré àwọn àwòrán, àwọn ẹ̀re, àwọn iyàwòrán, àwọn atẹjade tàbí àwọn ọ̀hún èlò amọ̀ tí ó jẹ́ tí àwọn oṣere ilẹ̀ Pólándì, ilẹ̀ Swídìn, ilẹ̀ Húngárì, ilẹ̀ Yukréìn àti ilẹ̀ Bràsíl asíko yí.[3][4]
Mùsíọ́mù, ó tún ní ìkójọpọ̀ àwọn ọ̀hún ìjà, tí ọ́ ní àwọn ọ̀kọ̀, idà, igi, ọfà.[1]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 https://www.poland.travel/en/rit/muzeum-miniaturowej-sztuki-profesjonalnej-henryk-jan-dominiak-w-tychach/
- ↑ https://web.archive.org/web/20211006104002/https://bip.mkdnis.gov.pl/media/download_gallery/20140319Muzea_utworzone_przez_osoby_fizyczne.pdf1397627824
- ↑ https://www.radio.katowice.pl/zobacz,13510,Jesien-z-agatami.html
- ↑ https://spis.ngo.pl/110948-muzeum-miniaturowej-sztuki-profesjonalnej-henryk-jan-dominiak-w-tychach