Mz Kiss
Ìrísí
Mz Kiss | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Akindele Justina Omowunmi |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kẹ̀sán 1992 Okitipupa, Nigeria |
Irú orin | Hip Hop, afropop |
Occupation(s) | singer, rapper |
Instruments | Vocals |
Years active | 2010–present |
Associated acts |
Akindele Justina Omowunmi (tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù kẹsàn ọdun 1992), tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Mz Kiss jẹ́ akọrin ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2][3][4][5][6][7][8]
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Mz Kiss sínú ìdílé ọjọ́ kínní oṣù kẹsàn-án ọdun 1996 ní Okitipupa, ìjọba àgbègbè ìbílè kan ní Ìpínlẹ̀ Òndó,[9][10] ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà, ó lọ ilé ìwé Kembus Nursery fún ẹ̀kọ́ Ìbẹ̀rẹ̀ àti , Abeokuta Grammar School ti Ìpínlè Ogun fún ẹ̀kọ́ Sẹ́kọ́ndìrì kí ó tó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní ilé-ìwé National Open University of Nigeria, ó kọ́ nípa ìmọ̀ Ibaraẹnisọrọ tí a mọ̀ sí Mass Communication.
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Female rapper, Mz Kiss drops new album 'Street on the loose'". Thenet.ng. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "Some people go as far as wanting to kiss me —Mz Kiss". Vanguardngr.com. August 29, 2014. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "Mz Kiss rocks a Silver Ensemble in Birthday Photos!". Bellanaija.com. September 2, 2018. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "'Maybe Yung6ix Is Dead' – Mz Kiss Says". Nigeriafilms.com. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "All Eyes are on Mz Kiss as She Covers Mystreetz Magazine's Latest Issue". Bellanaija.com. December 10, 2018. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "Chidinma & Mz Kiss All Smiles As They Pose Together". 36ng.ng. December 7, 2015. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "15 Nigerian Female Rappers Who Changed The Game". Woman Nigeria. December 12, 2015. Archived from the original on March 13, 2019. Retrieved March 13, 2019.
- ↑ "Capital Hills didn't drop Chidinma for me, says Mz Kiss". Thepointng.com. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "Mz Kiss". boomplaymusic.com. Archived from the original on April 30, 2019. Retrieved March 11, 2019.
- ↑ "Female Wrapper MZ Kiss Narrates Pain Behind The Fame". Silverbirdtv.com. Archived from the original on March 19, 2019. Retrieved March 11, 2019.