Nọ́mbà adọ́gba àti aṣẹ́kù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ninu Imo mathematiki, gbogbo nọ́mbà odidi le je nomba adogba (even number) tabi nomba aseku (odd number) lona yi: ti o ba je odidi nomba ni opolopo meji, nomba na je nomba adogba bibeko yio je nomba aseku. Fun apere 4, 0, 8, 16 je nomba adogba bee si ni 1, 3, 7, 9, 11 je nomba aseku.

Akojopo awon nomba adogba se ko bayi:

Adọ́gba = 2Z = {..., −6, −4, −2, 0, 2, 4, 6, ...}.

Akojopo awon nomba toseku se ko bayi:

Aṣẹ́kù = 2Z + 1 = {..., −5, −3, −1, 1, 3, 5, ...}.

Isirosise pelu awon nomba adogba ati nomba aseku[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iropo ati Iyokuro[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • adogba ± adogba = adogba
  • adogba ± aseku = aseku
  • aseku ± aseku = adogba

Isodipupo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

adogba * adogba = adogba

adogba * aseku = adogba

aseku * aseku = aseku

Isepinpin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ti a ba sepinpin odidi nomba ki se dandan pe yio fun wa ni nomba odidi pada. Fun apere ti a ba sepinpin 1 pelu 4, esi re yio je 1/4 ti ki se nomba adogba tabi nomba aseku nitoripe awon nọ́mbà odidi nikan ni won le je adogba tabi aseku. Sugbon ti ipin ba je odidi nomba, yio je adogba ti afi ti nomba ti a pin (dividend) ni opolopo iye (factor) meji ju nomba ti a fi pin (divisor) lo.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]