Naeto C
Ìrísí
Naeto C | |
---|---|
Naeto C | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Naetochukwu Chikwe |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | The 'P', Super C |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Ìpínlẹ̀ ímo, Nàìjíríà |
Irú orin | Rap, Hip-hop |
Occupation(s) | Olórin, akọrin sílẹ̀ àti Rápà. |
Years active | 2006–present |
Labels |
|
Associated acts |
|
Naetochukwu Chikwe, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Naeto C, jẹ́ rápà ti orílẹ̀-èdẹ Nàìjíríà, olórin Afrobeat àti aṣagbátẹ́rù rẹ́kọ́ọ̀dù.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìlú Houston, ní Texas ni wọ́n bí i sí, àmọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria ni.[1] Gómínà Ìpínlẹ̀ Imo, Emeka Ihedioha yan Naeto C láti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ nígbà tí ó wá sí Ipinle Eko.[2]
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Archived copy". Archived from the original on September 28, 2013. Retrieved September 22, 2013.
- ↑ "Imo: Gov. Ihedioha names Kema Chikwe’s son, Naeto C special assistant". Daily Post. Retrieved June 21, 2019.