Nafisath Radji
Nafissath Radji (tí a bí 2 Oṣù Kẹjọ ọdún 2002 ní Porto-Novo) [1] jẹ olùwẹ̀wẹ̀ ará ìlú Benin .
O díje nínú ìṣẹ̀lẹ̀ girls 50 metre backstroke ni 2018 summer youth Olympics tí ó wáyé ní Buenos Aires, Argentina. [2] O ko pé láti díje nínú semi finals. [2]
Ní ọdún 2019, ó represented Benin ni world Aquatics championships ti o wáyé ní Gwangju, South Korea. Ó díje nínú ìṣẹ̀lẹ̀ women's 50 metre freestyle. [3] ó kó síwájú láti dije nínú semi finals. [3] ó tún díje nínú ìṣẹ̀lẹ̀ women's 50 metre backstroke. Ní ọdún kanná, ó tún represented Benin ní 2019 African Games tí ó wáyé ní Rabat, Morocco. [4]
Ní ọdún 2021, ó díje nínú ìṣẹ̀lẹ̀ women's 50 meter freestyle ni 2020 summer Olympics tí ó wáyé ní Tokyo, Japan. [5] Àkókò rẹ̀ tí àwọn àáyá 29.99 nínú ooru rẹ̀ kò yẹ fún àwọn semi finals [6]
Ó represented Benin ní 2022 World Aquatics Championship tí o wáyé ni Budapest, Hungary. [7] Ó díje nínú women's 50 metre freestyle atí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ women's 100 metre freestyle . [7]