Narok
Ìrísí
Narok | |
---|---|
Town | |
Lua error in Module:Location_map at line 420: attempt to compare nil with number. | |
Coordinates: Lua error in package.lua at line 80: module 'Module:ISO 3166/data/KE' not found. | |
Country | Kenya |
County | Narok County |
Narok (tí àwọn mìíràn mọ̀ sí Ìlú Narok) jẹ́ ìlú kan ní ìwọ̀ oòrùn Nairobi tí ó sì ń gbé ọ̀rọ̀ ajé Kenya ga ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀ èdè náà. Narok jẹ́ Olú-ìlú Narok County ó sì jẹ́ àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé agbègbè. Ìlú náà ní olùgbé tí ó tó ẹgbẹ̀rún ogójì ènìyàn. Ìlú Narok ni ìlú tí ó tóbi tí ènìyàn má kàn kẹ́yìn tí ènìyàn bá ń lọ láti Nairobi lọ sí pákì Maasai Mara àti Keekorok Lodge. Ọ̀nà tí owó fi ń wọlé ní ìlú Narok láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn ni iṣẹ́ àgbẹ̀, kùsà àti pápá ìṣeré bọ́ọ̀lù tí ó wà níbẹ̀
Ètò ẹ̀kọ́ ìlú Narok
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìlú Narok ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ìwé aládàáni àti ti ìjọba.
Ilẹ́ ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ti ìjọba
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Masikonde Primary School
- Ole Sankale Boarding School
- St. Mary's Primary School
- St. Peter's Primary
- Lenana Primary School
- Ilmashariani Primary School
Private Primary Schools:
- St. Peters Academy
- Narok County Academy
- Ongata School
- Nasaruni Academy for Maasai Girls
Ilé ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ aládàáni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Narok Boys' High School.
- Maasai Girls' High School.
- Ole Tipis Secondary School
- St Mary's Secondary School.
Private Secondary Schools:
- St. Stephen Nkoitoi Secondary School
- Limanet Secondary School
Colleges
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Narok Teachers Training College
- Narok West Technical Training Institute
- Ludepe Teachers College [1]
- Lusaka Institute of Science and Technology
- Narok West Institute of Professional Studies [2]
- WE College [3]
Yunifásítì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilé ìwé Kristíẹ́nì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Bible College, Bisset Bible College
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ludepe Teachers College - Kenyaplex.com". www.kenyaplex.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-07-23. Retrieved 2019-08-18. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Nyamwembe, Denis. "KASNEB accredited institutions: Conditions for Accreditation, Full Accreditation, Interim Accreditation and Accreditation in Progress | Jambo News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-08-18. Retrieved 2019-08-18. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Kenya: First Lady Champions Education Opportunities for Vulnerable Girls and Women". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-18. Archived from the original on 2019-07-19. Retrieved 2019-08-18. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Kiplagat, Robert (2019-02-09). "Disquiet at Maasai Mara University following corruption exposé". Standard Media (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-02-01. Retrieved 2020-02-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)