Jump to content

Nasir ol Molk Mosque

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nasir ol Molk Mosque

Inside view

Basic information
Location Ìránì Shiraz, Iran
Province Fars Province
Municipality Shiraz County
Status Active
Architectural description
Architectural type Mosque
Architectural style Iranian architecture
Year completed 1888

Nasir ol Molk Mosque (Persian: مسجد نصیر الملک – Masjed e Nasir ol Molk‎‎), tí wọ́n tún mọ̀ sí  Mọ́ṣáláṣí Aláwọ̀ Pupa Fẹ́ẹ́rẹ́, jẹ́ mọ́ṣáláṣí ìbílẹ̀ ní Shiraz, Iran. Ó wà ní agbèègbè  Gowad-e-Arabān nítòsí Šāh Čerāq Mosque. Mọ́ṣáláṣí yìí ní gílásì aláwọ̀ àràbarà tí ó sí ṣe àfihàn àwọn èròjà ìbílẹ̀ bíi Panj Kāse ("marún tí ó tẹ̀") . Wón máa ń sàbà pèé ní Mọ́ṣáláṣí Aláwọ̀ Pupa Fẹ́ẹ́rẹ́,[1] nítorí lílo áwọ̀ pupa fẹ́ẹ́rẹ́ sílẹ̀ fún ẹ̀ṣọ́ inú rẹ̀.[2]

Wọ́n kọ́ mọ́ṣáláṣí yìí nígbà àkókò Qajar, wọ́n sì ń lòó lábẹ́ ààbò Endowment Foundation of Nasir ol Molk. Wọ́n kọ́ọ láàrín Ọdún 1876 sí 1888 nípa àṣẹ Mirzā Hasan Ali (Nasir ol Molk) tí ó jẹ́ ọba Qajar.[3] Àwọn aṣàpẹẹrẹ ayàwòrán ni Mohammad Hasan-e-Memār, ayàwòrán ọmọ orílẹ̀ èdè Iran, àti Mohammad Rezā Kāshi-Sāz-e-Širāzi.[4]

Àtúnṣe, ààbò, àti ìtọ́jú ohun ìṣẹ̀báyé yìí wà ní ìṣàkóso Endowment Foundation of Nasir ol Molk.

ibi ìṣàfihà fọ́tò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Media related to Nasirolmolk mosque ní Wikimedia Commons

  • List of Mosques in Iran
  • Architecture of Iran

Àjápọ̀ látìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Mosque of Whirling Colours: A Mixture of Architecture and Art in Nasīr al-Mulk Mosque in Shiraz, Iran Archived 2016-05-11 at the Wayback Machine., Cem Nizamoglu, MuslimHeritage.com
  2. CNN: Why your next vacation could be in Iran, Frederik Pleitgen – July 14, 2015
  3. Stunning Mosque In Iran Becomes A Magnificent Kaleidoscope When The Sun Rises, DeMilked Magazine
  4. Patricia L. Baker; Hilary Smith; Maria Oleynik (2014). Iran. Bradt Travel Guides. pp. 185–. ISBN 978-1-84162-402-0. http://books.google.com/books?id=RT0bAgAAQBAJ&pg=PA185.