Nasiru L. Abubakar
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Nasiru ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù kẹsàn-án ọdún 1977, [1] ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá Kaduna ní ìpínlẹ̀ Kaduna. Nasiru kẹ́kọ̀ọ́ gboyè PGD nínú ẹ̀kọ́-ìmọ̀ Mass Communication ní BUK, gboyè PGD nínú ẹ̀kọ́-ìmọ̀ Ìbáṣepọ̀ orílẹ̀-èdè àti Diplomacy ní àfikún sí ẹ̀kọ́ HND nínú ẹ̀kọ́-ìmọ̀ Mass Communication ní Kaduna Polytechnic, ní ìpínlẹ̀ Kaduna.[2]
Oníṣẹ́-ìròyìn
Nasiru bẹ̀rẹ̀ ìṣe ìròyìn gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ tí ó yàn láàyò ní ABG Group. Ó ṣiṣẹ́ fún ìgbà ráńpẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òǹkọ́ṣẹ́ lábẹ́ àmójútó pẹ̀lú KSMC ní ìlu Kaduna kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ oníwé-ìròyìn Daily Trust lákọ̀ọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ arakẹni ní oṣù mẹ́jọ 2000 kí ó tó wá di òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ gan ní ọdún 2004.[3][4] Ní Daily Trust, Ó jẹ́ aṣojú yàn ayẹ̀ròyìn wò (ní Sátidé) ní ọdún 2012, kí wọ́n tó dá a padà sí igbákejì ayẹ̀ròyìn wò Daily. Ní ọdún 2014 [5] kí wọ́n tó bòǹtẹ̀lú gẹ́gẹ́ bíi ayẹ̀ròyìn wò ní ọdún 2016.[6][7][8] Gẹ́gẹ́ bí ayẹ̀ròyìn wò, ó gba àmì-ẹ̀yẹ tí ayẹ̀ròyìn wò jùlọ tí ọdún náà ní ọdún 2016[9][10] tí ìwé-ìròyìn Daily sì gba àmì-ẹ̀yẹ ìwé-ìròyìn tí ọdún náà.[11][12]
Ní ọdún 2019, wọ́n yan Nasiru gẹ́gẹ́ bíi olùṣàkóso ayẹ̀ròyìn wò tí Daily Trust.[13][14] Ó fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 2020 láti lọ dára pọ̀ mọ́ Dateline Nigeria gẹ́gẹ́ bíi Olú-ayẹ̀ròyìn wò.[15][16][17][18]
Ó máa ń kó ìròyìn fún Gamji.com láti ọdún 2015[19][20] [21] ó sì máa ń dá sí ti àwọn ilé-iṣẹ́ yòókù.[22]
- ↑ "Nasiru Lawal - Editor in Chief at Dateline Nigeria". Apollo.io. Retrieved 2022-06-27.
- ↑ "Kaduna train attack: Abductors release photos, families identify captives". BluePrint. Retrieved 2022-04-27.
- ↑ "Fuel Crisis - Filling Stations Turn Black Market Outlets". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 May 2009. Retrieved 6 March 2022.
- ↑ "Video Shows Ex-Commissioner's Execution, by Nasiru L. Abubakar". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 August 2009. Retrieved 6 July 2022.
- ↑ "Nigeria: Daily Trust Appoints Acting Editor". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 November 2014. Retrieved 6 July 2022.
- ↑ "Nasiru L. Abubakar is now the substantive Editor of Daily Trust". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 February 2016. Retrieved 6 July 2022.
- ↑ "Celebration Of Kabiru Yusuf’s Election As NPAN". Tribune (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 May 2021. Retrieved 16 January 2022.
- ↑ "Kaduna: FRCN Management Condoles Immediate Past NUJ Kaduna Chairman Over Demise Of Father". News Reservoir (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 April 2022. Retrieved 1 March 2022.
- ↑ "Nigeria Newspaper Awards... And the Winner Is?". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 December 2016. Retrieved 6 June 2022.
- ↑ "The Nation confirms class with harvest of 13 awards at NMMA". The Nation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 December 2016. Retrieved 21 December 2021.
- ↑ "Daily Trust wins 2016 Newspaper of the year award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 13 July 2022.
- ↑ "Winners of Nigeria Media Merit Award". Punch Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 6 June 2022.
- ↑ "Media Trust appoints new Editor-in-Chief". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 30 December 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Media Trust staff eulogize outgoing managing, production editors". Press Reader (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 31 December 2021.
- ↑ "Media Trust appoints new Editor-in-Chief". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 30 December 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Former Daily Trust editors join Dateline Nigeria". Daily Nigerian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1 December 2020. Retrieved 30 December 2020.
- ↑ "Former Daily Trust editors join Dateline Nigeria - The Cable". The Cable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1 December 2020. Retrieved 30 December 2020.
- ↑ "Nasiru L. Abubakar join Dateline Nigeria as Editor in Chief". PR Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1 December 2020. Retrieved 30 December 2020.
- ↑ "Letter to ‘President’ Jerry Gana, by Nasiru L. Abubakar". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 September 2015. Retrieved 9 June 2021.
- ↑ "Bukar’s Legitimate Ignorance By Nasiru Lawal". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2016.
- ↑ "Between Gumi and Nigerian Politicians, by Nasiru L. Abubakar" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 September 2007. Retrieved 6 February 2021.
- ↑ "Imam Dahiru Lawal Abubakar: 1970-2022". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2022.
- ↑ "Letter to ‘President’ Jerry Gana, by Nasiru L. Abubakar". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 September 2015. Retrieved 9 June 2021.
- ↑ "Bukar’s Legitimate Ignorance By Nasiru Lawal". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2016.
- ↑ "Between Gumi and Nigerian Politicians, by Nasiru L. Abubakar" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 September 2007. Retrieved 6 February 2021.
- ↑ "Imam Dahiru Lawal Abubakar: 1970-2022". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2022.