Jump to content

Nasser Al Qasabi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nasser Al Qasabi
Ọjọ́ìbíNasser bin Qassim Al Qasabi
ناصر بن قاسم القصبي

28 Oṣù Kọkànlá 1961 (1961-11-28) (ọmọ ọdún 63)
Riyadh, Saudi Arabia
Iṣẹ́Actor, comedian
Ìgbà iṣẹ́1984–present
Olólùfẹ́Badryah El-Bishr[1]

Nasser bin Qassim Al Qasabi (Lárúbáwá: ناصر بن قاسم القصبي‎, tí wọ́n bí ní 28 November 1961 ní Riyadh, Saudi Arabia) jẹ́ òṣèrékùnrin ti ilẹ̀ Saudi Arabia.[2] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré ní ọdún 1984, ó sì gbajúgbajà fún ẹ̀dá-ìtàn tó máa ń kó nínú eré Tash Ma Tash (Arabic: طاش ما طاش[3]). Ní ọdún 2012, Nasser wà lára àwọn adájọ́ fún ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ti Arabs Got Talent.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. المحارب, سعد (10 September 2007). "بدرية البشر للعربية.نت: الفتوى ضد "طاش ما طاش" لم تجد صدى بالسعودية". Alarabiya.net (in Èdè Árábìkì). Archived from the original on 29 July 2015. Retrieved 12 June 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Nasser Al Qasabi: The Master of Social Satire". deven.majalla.com (in Èdè Árábìkì). Archived from the original on 2021-10-28. Retrieved 2021-10-28. 
  3. "The Return of Tash 16 on MBC". Waleg. August 11, 2009. Archived from the original on 4 April 2012. https://web.archive.org/web/20120404014233/http://www.waleg.com/archives/017438.html. Retrieved 25 May 2011.