Nat King Cole

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Nat King Cole
Fáìlì:Nat-king-cole.jpg
Background information
Birth name Nathaniel Adams Coles
Genres Vocal jazz, swing, traditional pop, jump blues, vocal
Occupations Singer-songwriter, pianist
Instruments Piano, guitar
Years active 1935–1965
Labels Decca, Capitol
Associated acts Natalie Cole, Frank Sinatra, Dean Martin

Nathaniel Adams Coles (March 17, 1919 – February 15, 1965), to gbajumo nibise bi Nat "King" Cole, jeolorin ara Amerika to koko gbajumo bi okan ninu awon atepiano jazz. Botilejepe o yorisirere bi atepiano, 0hun baritonu re ni awon eniyan se mo, to unlo lati korin larin agbo nla ati awon iru orin jazz. Ohun ni eni alawodudu ara Amerika akoko to je agbalejo ere orisirisi lori telifison, beesini o ti gbajumo kakiri agbaye nitori iku aitojo re; o je gbigba bi ikan ninu awon olorin pataki to koja ni orile-ede Amerika.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]