Jump to content

National Commission for Persons with Disability

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


National Commission for Persons with Disability
overview
Formed 2012 (2012)
Jurisdiction Federal Government of Nigeria
Headquarters Abuja, FCT, Nigeria
executive James Lalu, Executive Secretary;
Parent Federal Ministry of Humanitarian Affairs, Disaster Management and Social Development
Website
ncpwd.gov.ng/index.html/index.html

National Commission for Person with Disabilities (NCPD) jẹ́ àjọ kan lòrìlẹ̀-èdè Naijiria. Ọdún 2012 ni a gbé àjọ yìí sílẹ̀.[1]

Èròńgbà àjọ yìí ni láti dẹ́kun ìwà yíya àwọn èèyàn tó ní àleébù tàbí ìlera sọtọ̀, àti láti jẹ́ kí irú àwọn èèyàn báyìí ní ẹ̀tọ́ àti àǹfààní kan náà pẹlú àwọn akẹgbẹ́ wọn tí ò ní àleébù kọkan lára.[2][3]

Wọ́n dá àjọ NCPD sílẹ̀ nílànà òfin ọdún 2019 tí ó ní ṣe pẹ̀lú dídẹ́kun ìwà yíya àwọn èèyàn tó ní àleébù tàbí ìlera sọtọ̀, àti láti ri pé wọ́n kópa nínú gbogbo ẹ̀ka iṣẹ́ láàárín ìlú.[4][5]

Àwọn èróńgbà wọn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Díẹ̀ lára àwọn èróńgbà àjọ yìí ni;

  • Láti pèsè agbègbè tó ṣe é gbé fún àwọn èèyàn tó ní àleébù tàbí ìlera.
  • Láti ṣe àkójọ àti ìmójútó détà àwọn èèyàn tó ní àleébù tàbí ìlera.
  • Láti ṣe ìpèsè ìmọ̀ràn tó péye fún ẹ̀ka àjọ náà.
  • Láti gbétò oríṣiríṣi kalẹ̀ ní Siẹrra Léònè.

Ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kìíní, ọdún 2019 ni ààrẹ Muhammadu Buhari bọwọ́ lùwé láti ṣe ìdásílẹ̀ àjọ NCPD lábẹ́ òfin 2018. Díẹ̀ lára àwọn ohun tí òfin yìí wà fún ni ríró àjọ yìí lágbára láti múgbòrò, àti dábòòbò àwọn èèyàn tó ní àleébù tàbí ìlera.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Home". NCPD (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-29. 
  2. "Farouq inaugurates governing council of Nat'l Commission for Persons with Disabilities". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-22. Retrieved 2022-03-29. 
  3. "The significance of Disability Commission". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-21. Archived from the original on 2022-03-29. Retrieved 2022-03-29. 
  4. "2019 Disability Day: FG to establish National Commission for Persons with" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-03. Retrieved 2022-03-30. 
  5. Abdullateef, Ismail (2020-07-07). "Establishment Of National Commission For Persons With Disability On Course - Farouq". Federal Ministry of Information and Culture (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-30. 
  6. "About". NCPWD. 2019-01-17. Archived from the original on 2022-02-05. Retrieved 2022-03-30.