National Hospital, Abuja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

National Hospital Abuja jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé ìwòsàn ní Abuja, FCT, Nàìjíríà.

A dá ilé ìwòsàn náà kalẹ̀ lábé ètò Family Support Programme initiative[1]. Abdulsalami Abubaka ni ẹni tí ó ṣẹ ìsílé ilé ìwòsàn náà ní 22 May 1999.[2] Orúkọ tí wọ́n kọ́kọ́ fún ilé ìwòsàn náà ni National Hospital For Women And Children. Ìjọba fún ilé ìwòsàn náà ni orúkọ tí ó ún jẹ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù karùn-ún(10 May) ọdún 2000.[3].

Àwọn Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Atoyebi, Olufemi. "National Hospital losing focus –Maryam Abacha". The Punch (Nigeria). Retrieved 31 October 2020. 
  2. "Introduction Archived 2021-03-04 at the Wayback Machine.." National Hospital Abuja. Retrieved on 12 February 2009.
  3. "About Us Archived 2009-03-12 at the Wayback Machine.." National Hospital Abuja. Retrieved on 12 February 2009.