National Museum fún orin (Burkina Faso)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

National Museum fún orin Music jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní Ouagadougou, (Burkina Faso), ó wà ní Oubritenga Avenue ní ìwọ̀ oòrùn ilé-ìwé Phillipe Zinda Kabore.

Ibi tí ó jẹ́ ilé tẹ́lẹ̀rí fún àwọn Association for the Development of African Architecture and Urban Planning (ADAUA) ni wọ́n padà sọ di Musíọ́mù. Ilé náà wà ní àárín ìlú, ó sì jẹ́ ibi tí àwọn ará ìlú le tètè dé.

Àwọn òun èlò orin bi aerophones, membranophones, idiophones àti chordophones tí ó ti fẹ́ ma párẹ́ ni ó wà níbẹ̀. Àwọn oun èlò orin yìí jẹ́ èyí tó kù nínú irú wọn. Àwọn míràn nínú wọn sì ti lé ní igba ọdún.

Parfait Z. Bambara ni olórí musíọ́mù náà.