Jump to content

National Museum of Mauritania

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
National Museum of Mauritania
Musée National de Nouakchott
Ilé musíọ́mù náà
Building
LocationNouakchott, Mauritania
Coordinates18°5′8″N 15°58′29″W / 18.08556°N 15.97472°W / 18.08556; -15.97472Coordinates: 18°5′8″N 15°58′29″W / 18.08556°N 15.97472°W / 18.08556; -15.97472

National Museum of Mauritania, tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí National Museum of Nouakchott (Faransé: Musée National de Nouakchott), jẹ́ musíọ́mù àgbà orílẹ̀ èdè Mauritania, tí ó wà ní Nouakchott. Ó wà ní gúúsù apá ìwọ oòrùn Hotel Mercure Marhaba, ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà Hotel de Ville, àríwá ìwọ̀ oòrùn Parc Deydouh, àti àríwá Mosque Ould Abas.[1]

Musíọ́mù náà jẹ́ ilé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohùn pàtàkì ayé àtijó tí wọ́n padà wú jáde láti inú ilẹ̀.[2]

Ilé Musíọ́mù náà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé musíọ́mù náà jẹ́ ilé alájà méjì tí àwọn aráa China kọ́ in 1972. Ilé náà tún jé ilé fún Mauritanian Institute of Scientific Research, the Mauritanian Manuscripts Conservation Centre àti Ilé ìkàwé Mauritania.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. The National Museum of Mauritania Archived 2021-07-09 at the Wayback Machine..
  2. "Mauritania museums". Africa.com. Archived from the original on 1 January 2013. Retrieved 10 March 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)