National Museum tí orílè-èdè Nàìjíríà
Ìrísí
Musiomu Orilẹ-ede Naijiria jẹ ile musiọmu ní ìpínlè Èkó, orílè-èdè Nàìjíríà Ile-išẹ musiọmu naa ni akojọpọ àwon ère ati aworan nlá ni Naijiria, pẹlu awọn awọn ohun-ọṣọ. [1] Musiomu náà wa ni Onikan, Lagos Island, Ipinle Eko. Ówà labé idari National Commission for Museums and Monuments.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kenneth Murray dá Musiomu náà kalè ní odún 1957, a da Musiomu náà kalè láti jé ilé ipamo fún àwon ohun esó àti ohun àsà orílè-èdè Nàìjíríà.[2]
Àwon atojo òhun èsó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Musiomu náà jé ilé fún àwon ohun esó àti àsà bi egbèrún metadinlagota, [3] àwon ohun àsà bi ibon, aso egungun, ìlù àti ere.
Ibi Àwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]-
Benin mask; ivory
-
Bronze ceremonial pot; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Bronze ceremonial vessel in form of a snail shell; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Bronze ornamental staff head; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Bronze pot; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Bronze pot; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Cresentric bowl; bronze; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Bronze intricate ornamental staff head; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
Intricate bronze ceremonial pot; 9th century; from Igbo-Ukwu
-
the car in which Murtala Mohammed was assassinated
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nations Encyclopedia
- ↑ Board, Editorial (March 16, 2016). "Rehabilitating the National Museum - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved September 10, 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "The National Museum of Lagos Six Enthralling Masterworks at the National". RefinedNG. October 9, 2021. Retrieved September 10, 2022.