Neith
Neith | |||||
---|---|---|---|---|---|
Script error: The module returned a nil value. It is supposed to return an export table. The Egyptian goddess Neith, the primary creator, bearing her war goddess symbols, the crossed arrows and shield on her head, the ankh, and the was-sceptre. She sometimes wears the Red Crown of Lower Egypt. | |||||
Name in hieroglyphs |
| ||||
Major cult center | Sais, Esna | ||||
Symbol | bow, shield, crossed arrows, ankh, loom, mummy cloth | ||||
Consort | usually none, later paired with Ptah-Nun, Khnum,[1] Set[lower-alpha 1] | ||||
Offspring | Sobek,[2] Ra,[3] Apep,[lower-alpha 2] Tutu,[4] Serket |
Neith /ˈniː.ɪθ/ ó jẹ́ èyí tí ó ba ni lẹ́rù"; Coptic: ⲛⲏⲓⲧ;[5] bákannáà jẹ́ èpè Nit, Net, tàbí Neit) jẹ́ àwọn ancient Egyptian deity ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀. Wọ́n sọ pé ó Alàkọ́kọ́ àti olú aṣẹ̀dá, tí ó dà àgbáyé àti gbogbo àwọn ohun inú rẹ̀, tí ó sì ń ṣàkóso bí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́. Ó jẹ́ òrìṣàbìnrin fún àgbáyé, àyàmọ̀, Ọgbọ́n, omi, àwọn odò, àwọn ìyá, ọmọ bíbí, ọdún ṣíṣe, ríru, àti ogun.
Neith jẹ́ tutelary deity ti Sais níbi tí wọ́n fi ẹgbẹ́ òkùkù rẹ̀ sọ lẹ̀ sí ìwọ̀-oòrùn Nile Delta ti Lower Egypt. Wọ́n jẹ́rìí rẹ̀ ní Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ẹ Dynasty Àkọ́kọ́.[6] Neith tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà aláàbò mẹ́ta ti ìlà-oòrùn ìlú ti Latopolis tàbí Esna (Snē) [7][8]). Latopolis wà ní ìwọ̀-oòrùn etídò ti Odò Nile ọ̀pọ̀ 55 kilometres (34 mi) ìlà-oòrùn ti Luxor (Thebes).
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Najovits, Simson R. (May 2003). Egypt, Trunk of the Tree, Vol. I: A Modern Survey of and Ancient Land. Algora Publishing. ISBN 9780875862347. https://books.google.com/books?id=Y72qrAmKcfEC&q=heka%20khnum%20triad&pg=PA102.
- ↑ Fleming & Lothian, op. cit.
- ↑ Lesko, Barbara S. (1999). The Great Goddesses of Egypt. University of Oklahoma Press. pp. 60–63. ISBN 0-8061-3202-7. https://archive.org/details/greatgoddessesof00lesk/page/60.
- ↑ www.globalegyptianmuseum.org retrieved March 18, 2009
- ↑ "ⲛⲏⲓⲧ - Wiktionary". en.wiktionary.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-01.
- ↑ Shaw & Nicholson, op, cit., p.250
- ↑ Richter, Barbara A. (2016-04-15) (in en). The Theology of Hathor of Dendera: Aural and Visual Scribal Techniques in the Per-Wer Sanctuary. ISD LLC. ISBN 9781937040529. https://books.google.com/books?id=HAlPDgAAQBAJ&pg=PA74.
- ↑ Kaper, Olaf E. (2003) (in en). The Egyptian God Tutu: A Study of the Sphinx-god and Master of Demons with a Corpus of Monuments. Peeters Publishers. ISBN 9789042912175. https://books.google.com/books?id=kiQrO70c7nYC&pg=PA192.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found