Neon Adejo
Neon Adejo Yunisa, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Neon Adejo ( tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin lélógún oṣù kẹwàá) jẹ́ akọrin ihinrere ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olórin àti aṣáájú ìsìn tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí orin “Eze Ebube”. [1]
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Neon Adejo ni ọjọ́ kẹrin lélógún Oṣù Kẹwàá ní ìkòyí, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Òun ni àkọ́bí nínú àwọn ọmọ mẹ́fà nínú ìdílé àwọn òbi rẹ̀. [2] Ó dàgbà sínú ẹ̀sìn Mùsùlùmí ṣùgbọ́n ó padà di ẹlẹ́ṣin kìrìsìtẹ́nì
Ní 2023 ó kẹ́kọ̀ọ́ gba ìmò oyè Báṣẹ́lọ̀ Degree ní HISTORY AND INTERNATIONAL RELATIONS Kogi State University, Nigeria
Iṣẹ orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọ ọdún mẹ́tàlá ni Adejo bẹ̀rẹ̀ orin ṣùgbọ́n ọdún 2014 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní pẹrẹwu Ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin ákọ́kọ́ rẹ̀ tí akọ́lẹ̀ TELL THE WORLD ní ọdún 2020 tí ó ní àwọn orin mẹ́wàá.
lẹ́hìn ọdún kan , ní Oṣù Kẹta ọdún 2021, Adejo ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin kejì rẹ̀ àti EP àkọ́kọ́ tí akole Orin Ọpẹ́ tí ó ní àwọn orin márùn-ún pẹ̀lú Eze Ebube àti Breathe On Me inclusive. [3]
Aworan aworan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn àwo -orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Akọle | Ọjọ Tu silẹ | Awọn alaye |
---|---|---|
Nkankan bikose ihinrere | Oṣu Kẹsan 2022 |
|
Awọn orin ti Ọpẹ (EP) | Oṣu Kẹta ọdun 2021 |
|
Sọ fun agbaye | Oṣu Kẹrin Ọjọ 2020 |
|
- Mu kuro (2018)
- Chinecherem (2019)
- Onyenemema (2020)
- Amin (2021)
- Eze Ebube (2021)
- Eze Ebube II (2022)
Odun | Eye | Ẹka | Abajade | Ref |
---|---|---|---|---|
Ọdun 2023 | Eye Achievers Kingdom | Gbàá | [4] | |
Awọn akọle | Gbàá | |||
GX Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "How Eze Ebube was birthed, by artiste Neon Adejo". https://thenationonlineng.net/how-eze-ebube-was-birthed-by-artiste-neon-adejo/.
- ↑ "Neon Adejo And The Birth Of Afroworship". https://independent.ng/neon-adejo-and-the-birth-of-afroworship/.
- ↑ Songs of Gratitude - EP by Neon Adejo
- ↑ "Neon Adejo, Mike Abdul, Naomi, Ariyo win at Kingdom Achievers Award". https://thenationonlineng.net/mike-abdul-naomi-ariyo-win-at-kingdom-achievers-award/.