New Edition
Ìrísí
New Edition | |
---|---|
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | N.E. |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Boston, Massachusetts, U.S. |
Irú orin | |
Years active | 1978–1990,[4][5] 1996–97, 2002–present |
Labels | |
Associated acts | |
Members | Ricky Bell Michael Bivins Ronnie DeVoe Bobby Brown Johnny Gill Ralph Tresvant |
New Edition ni ẹgbẹ́ olórin R&B ará Amẹ́ríkà láti àdúgbò Roxbury ní Boston, Massachusetts, tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1978.[5] Wọ́n gbajúmọ̀ gan ní ìgbà àwọn ọdún 1980. Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àkọ́kọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ ni Ricky Bell, Michael Bivins, Ronnie DeVoe, Bobby Brown àti Ralph Tresvant. Johnny Gill dara pọ̀ mọ́ wọn lọ́jọ́ wájú. Nínú àwọn orin wọn tó gbajúmọ̀ ni "Candy Girl," "Cool It Now," àti "Mr. Telephone Man".[6]
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Huey, Steve. "New Edition – Artist Biography". AllMusic. All Media Network. Retrieved July 27, 2016.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedMTV
- ↑ Carter, Kelley L. (10 August 2008). "5 Things You Can Learn About ... New jack swing". Chicago Tribune. Archived from the original on 7 May 2012. https://web.archive.org/web/20120507154347/http://articles.chicagotribune.com/2008-08-10/news/0808080318_1_new-edition-new-jack-city-swing. Retrieved 26 July 2016.
- ↑ "You Say It's Your Birthday, New Edition, and Bell Biv Devoes". Archived from the original on 2019-10-24. Retrieved 2019-10-24.
- ↑ 5.0 5.1 "‘The New Edition Story’ Part One: Humble Beginnings To Harsh Realities". Essence. 2017-01-25. Archived from the original on 2022-06-05. Retrieved 2019-10-24.
- ↑ "New Edition Chart History". Billboard.com.