Jump to content

Ngozi Alaegbu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ngozi Alaegbu
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́University of Hamburg, Germany
Iṣẹ́Broadcast Journalist, TV Presenter
OrganizationArise TV

Ngozi Alaegbu jẹ́ akọròyìn àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán.[1] Ó ti ṣiṣẹ́ ní Degue Broadcasting Network (DBN), Television Continental (TVC). Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó sì ń ṣịṣẹ́ pẹ̀lú Arise TV.[2]

Ìgbésíayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaegbu kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ German ní University of Hamburg, Germany.[3] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nípasẹ̀ ṣíṣẹ iṣẹ́ pẹ̀lú DBN. Lẹ́yìn náà, ó lọ sí TVC, níbi tí ó ti lo àwọn ọdún díẹ̀ ṣáájú kí ó tó fi ipò náà sílẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ọdún 2019.[4] Ìṣípòpadà Alaegbu sí Arise TV ṣẹlẹ̀ ní oṣụ̀ kejì, ọdún 2020.[5]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaegbu gba àmì-ẹ̀yẹ ti akaròyìn tó dára jù lọ lórí ẹ̀rọ̀ amóhu ̀nmáwòrán ní ọdún 2021, èyí tó jẹ́ ti Nigeria Media Merit Awards.[6] Wọ́n to orúkọ rẹ̀ sí ipò karùndínlógún lára àwọn obìnrin alágbára jù lọ nínú iṣẹ́ akọ̀ròyìn, láti ọ̀wọ́ àwọn Women in Journalism, ní ọdún 2021.[7]

Ìgbésí ayé ara ẹni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaegbu jẹ́ ìyà àti ìyá-ìyá, ìyẹn ni pé àwọn ọmọ rẹ̀ ti ń bímọ, ó sì ti ní àwọn ọmọ-ọmọ.[8]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Reporter (2017-07-25). "TVC Newscaster, NGOZI ALAEGBU •How She Fell In Love With Broadcasting". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-01. 
  2. Olowookere, Dipo (2020-02-17). "Ngozi Alaegbu Joins Arise TV After Leaving TVC | Business Post Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-01. 
  3. Reporter (2017-07-25). "TVC Newscaster, NGOZI ALAEGBU •How She Fell In Love With Broadcasting". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-01. 
  4. Admin (2019-08-29). "Ngozi Aaegbu resigns from TVC?". National Daily Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-01. 
  5. Olowookere, Dipo (2020-02-17). "Ngozi Alaegbu Joins Arise TV After Leaving TVC | Business Post Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-01. 
  6. "PUNCH wins Newspaper of the Year, 10 other awards at NMMA". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-11-01. Retrieved 2021-12-01. 
  7. "Ijeoma Nwogwugwu, Stella Din, Kadaria Ahmed named among 25 most powerful Nigerian female journalists". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-02. Retrieved 2021-12-01. 
  8. Korkus, Stella Dimoko. "OAP Ngozi Alaegbu Celebrates Birthday With Lovely New Photos Of Her Grand Daughters Et AL...". Retrieved 2021-12-01.