Nidhal Guiga
Ìrísí
Nidhal Guiga | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹta 1975 (1975-03-11) (ọmọ ọdún 49) |
Orílẹ̀-èdè | Tunisian |
Iṣẹ́ | Actress, writer, film director |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004-present |
Nidhal Guiga (tí wọ́n bí ní 11 Oṣù Kẹẹ̀ta, Ọdún 1975) jẹ́ òṣèrébìnrin, òkọ̀tàn, àti olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Tùnísíà