Nigeria Centre for Disease Control

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Nigeria Centre for Disease Control, NCDC (Gbọ̀ngàn Náìjíríà fún Ìjánu Àrùn) jẹ́ olórí àjọ ètò ìlera ìjọba àpapọ̀ tí ó ń bójú tó ètò àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àjọ yìí wà lábẹ́ ìṣàkóso ilé-iṣẹ́ ètò ìlera ìjọba àpapọ̀, Federal Ministry of Health (Nigeria) tí olú ilé iṣẹ́ àjọ náà sìn wà ní Abuja, Nigeria.[1][2] Ọ̀gbẹ́ni Chikwe Ihekweazu ní olórí àjọ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ .[3]

Pàtàki iṣẹ́ àjọ yìí ni láti dá ààbò bo ìlera gbogbo ará ìlú àti láti dẹ́kun ìlera àwọn ènìyàn nípa ìdarí àti ìdènà àwọn àjàkálẹ̀ àrùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4]Àjọ yìí tún wà fún ṣíṣe kòkárí bí àrùnkárùn kò ṣẹ ní gbìnàyá, nípa ṣíṣe àkójọ pọ̀ ìròyìn nípa àrùn kan, ṣe àgbéyẹ̀ ípa irú àrùn bẹ́ẹ̀ láti dènà ríràn ká wọn láwùjọ.

Olú ilé-isé NCDC

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nigeria Centre for Disease Control/ World Health Organization (NCDC/WHO) Map Resources for National Action Plan for Health Security (NAPHS) in 36 States and Federal Capital Territory (FCT)". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-01. Retrieved 2019-08-24. 
  2. siteadmin (2019-08-13). "Yellow Fever Outbreak: No Reagent In Nigeria, Government Sends Samples To Cote D’Ivoire". Sahara Reporters. Retrieved 2019-08-24. 
  3. "83 suspected cases of cholera recorded in Adamawa - NCDC". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-22. Retrieved 2019-08-24. 
  4. siteadmin (2019-08-13). "Yellow Fever Outbreak: No Reagent In Nigeria, Government Sends Samples To Cote D’Ivoire". Sahara Reporters. Retrieved 2019-08-24.