Nigeria Hockey Federation
Àdàkọ:Infobox sport governing body Nigeria Hockey Federation (NHF) jẹ́ àjọ tó ń ṣàkóso eré bọ́ọ̀lu aláfigigbá orí pápá field hockey ní orílẹ̀ èdè Nigeria. Ó wà ní abẹ́ IHF International Hockey Federation àti AHF African Hockey Federation. Olú iléeṣẹ́ NHF wà ní Abuja, Nigeria.
Engineer Obadiah Simon Nkom ní Ààrẹ NHF tí Chimezie Asiegbu jẹ́ akọ̀wé gbogboogbò.[1]
FIH ni àjọ tó má ń fòhùntẹ̀ lu orí pápá eré bọ́ọ̀lù aláfigigbá. Lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí pápá ìṣẹré tí àjọ FIH fòhùntẹ̀ lù ní Nàìjíríà.
The Nigeria Hockey men's national team[2] made history in January at the 2022 Africa Cup of Nations in Ghana finishing third at the tournament after a 4-2 win against Kenya. It was their first ever podium finish at the Africa Cup of Nations.
See also
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]References
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàkọ:Sports governing bodies in Nigeria Àdàkọ:National members of the International Hockey Federation
Àdàkọ:Fieldhockey-stub Àdàkọ:Sport-org-stub Àdàkọ:Nigeria-sport-stub