Jump to content

Nigerian Conservation Foundation

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nigerian Conservation Foundation
Nigeria Conservation Foundation Lekki
Formation1980
HeadquartersLekki, Lagos
Director GeneralDr. Muhtari Aminu-Kano
Websitehttps://www.ncfnigeria.org/

Àjọ Nigerian Conservation Foundation jẹ́ àjọ aládàáni kan tí ó ń ṣiṣẹ́ láti dáàbò bo àwọn ohun àlùmọ́nì àti ẹranko ní Nàìjíríà.[1] Shafi Edu ni ó dá ẹgbẹ́ náà kalẹ̀ ní ọdún 1980,wọ́n sì ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ́ káàkiri Nàìjíríà.[2] Olóyè Ede Dafinone ni alága ẹgbẹ́ náà lọ́wọ́ lọ́wọ́, Dókítá Muhtari Aminu-Kano sì ni adarí àgbà.[3]

Ara àwọn ọ̀lùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ náà ni Akintola Williams.[4] Wọ́n sọ Akintola Williams Arboretum ní Nigerian Conservation Foundation ti Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ̀le.[5] Ẹgbẹ́ náà ń síse pẹ̀lú àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga, àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti Sẹ́kọ́ndírì, àti pẹ̀lú àwọn ara ìlú láti mú ète wọn ṣe. Àwọn ònímọ̀ Sáyẹ́ǹsì nínú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn ma ń ṣe ìwádìí nípa àwọn agbègbè tí àwọn ẹranko inú igbó ń gbé.

NCF ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ àti àjọ bi World Wildlife Fund, International Union for Conservation of Nature, BirdLife International, Wetlands International, Fauna and Flora International, àti Wildlife Conservation Society.[6] [7] Wọ́n tún ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ilé isé Chevron àti BG Group láti mú ilosókè débá ilé-isé epo ròbì ní Nàìjíríà. NCF dá Lekki Conservation Centre kalẹ̀ ní 1990.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

In 1992, the National conservation Foundation was recognized by the UN Environmental Program, which added it to its Global 500 Roll of Honour, a group of individuals and organizations making important contributions to the environment.

According to Climate Score Card, "NCF is regarded as one of the best environmental NGOs in the country. Currently, they have projects in 9 different states ranging from the Participatory Forest Management Project in Taraba State to Management of Becheve Nature Reserve, Obudu Cattle Ranch, Obudu, Cross River State . Their best practice climate project would have to be the Biodiversity Action Plan (BAP) in Edo state."[2]

  1. "Nigerian Conservation Foundation (NCF) | International Land Conservation Network". www.landconservationnetwork.org. Archived from the original on 2022-10-17. Retrieved 2022-03-30. 
  2. 2.0 2.1 Hansen, Peter (2021-05-13). "Best Climate Practice Nigeria: Nigerian Conservation Foundation (NCF)". Climate Scorecard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-26. 
  3. "IUCN - Emmanuel Asuquo Obot (Nigeria)". www.iucn.org. Archived from the original on 2009-06-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "The Doyen at 91". The Punch. 2010-08-24. http://news2.onlinenigeria.com/news/breaking-news/56878-The-Doyen.rss. Retrieved 2011-06-01. 
  5. "Akintola Williams calls for forestry scholarships". Nigerian Conservation Foundation. Archived from the original on 2012-03-24. Retrieved 2011-06-01.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "NCF Nigeria". Archived from the original on 2009-05-14. Retrieved 2023-05-05. 
  7. "Nigeria - Nigerian Conservation Foundation". BirdLife International (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-22. Retrieved 2022-03-30.