Jump to content

Nike Folayan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nike Folayan
Ọjọ́ìbí1978
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Kent University of Sheffield
EmployerParsons Brinckerhoff
Gbajúmọ̀ fúnAssociation for Black and Minority Ethnic Engineers (AFBE-UK)

Dr Nike Folayan MBE tí a bí ní ọdún 1978 jẹ́ Chartered Engineer àti Telecommunications Engineering Consultant. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ àti alága fún Association for Black and Minority Ethnic Engineers[1] tí ó ń kéde ethnic diversity nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ ní UK.

Ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Folayan gboyè MEng nínú electronic engineering ní University of Kent, ó sì gboyè PhD nínú antenna design ní University of Sheffield.[2]

Lẹ́yìn tó gboyè PhD, ó dara pọ̀ mọ́ Mott MacDonald gẹ́gẹ́ bíi Communications Engineer.[3] Ibí ni ó ti ṣiṣẹ́ lórí radio design lóríṣiríṣi àti àwọn communications systems bíi CCTV àti àwọn ẹ̀rọ agbóhùn sáfẹ́fẹ́.[4] Ó dara pọ̀ mọ́ Parsons Brinckerhoff ní ọdún 2013 níbi tí ó ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Systems Integration Consultant.[4] Ó ṣiṣẹ́ lórí àwọn infrastructure projects bíi CrossRail àti ṣíṣàtúnṣe Victoria Station.[5] Ní ọdún 2016, wọ́n gbe lọ ipò Associate Director fún Communications and Control láàárín Railways Division of WSP.[6]

Ìkéde fún Ìtànkálẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2008, Folayan gba àmì-ẹ̀yẹ "Inspiring Leader within the Workplace".[7][8][9] Ní ọdún 2012, wọ́n ṣàfihàn Dr Folayan nínú Powerlist: Britain’s 100 most influential people of African and Caribbean heritage.[10] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùgbàlejò tí ó sọ̀rọ̀ ní Higher Education Academy STEM annual conference lọ́dún 2014.[11] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn trustee ní Engineering Development Trust àti ọmọ ẹgbẹ́ Science Council àti ẹgbẹ́ Transport for London.[12][13][14] Ó lọ́wọ́ sí ìtànkálẹ̀ Royal Academy of Engineer's. Ní ọdún 2017, Folayan sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ Institution of Engineering and Technology's "9 % is Not Enough".[15]

The Association for Black and Minority Ethnic Engineers

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nike Folayan àti àbúrò rẹ̀ Ollie Folayan ló ṣe ìdásílẹ̀ Association for Black and Minority Ethnic Engineers (AFBE-UK) lọ́dún 2007, wọ́n sì jẹ́ alága ìgbìmọ̀ náà.[16] Lọ́dún 2011, Vince Cable tí ó jẹ́ akọ̀wé fún State for Business, Innovation and Skills nígbà náà fara hàn ní AFBE-UK’s seminar lórí infrastructure ní UK.[17][18] Ní ọdún 2016, ó darí ètò kan tó rí sí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti yunifásítì lóríṣiríṣi ní ìlú London láti kópa nínú àwọn iṣẹ́ lóríṣiríṣi tí ó le ràn wọ́n lọ́wọ́.[19][20]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Home - Association For BME Engineers (AFBE-UK)". afbe.org.uk. Retrieved 2020-01-24. 
  2. "A sense of belonging in engineering - Create the Future" (in en-US). Create the Future. 2017-06-09. Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121072127/http://qeprize.org/createthefuture/sense-belonging-engineering/. 
  3. "Young, gifted and black" (in en). Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121125752/http://www.voice-online.co.uk/article/young-gifted-and-black?quicktabs_nodesblock=2. 
  4. 4.0 4.1 "People integration systems - The IET". www.theiet.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 21 January 2018. Retrieved 2018-01-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Female engineers: The women solving real-world problems" (in en-GB). The Independent. 2015-10-19. https://www.independent.co.uk/extras/jobs/female-engineers-the-women-solving-real-world-problems-a6699661.html. 
  6. "A fascination for TVs inspired me to be an engineer: Nike Folayan - Melan Mag" (in en-GB). Melan Mag. 2017-10-27. http://melanmag.com/2017/10/27/a-fascination-for-tvs-inspired-me-to-be-an-engineer-nike-folayan/. 
  7. "Enterprising women shine at Precious Awards - Ethnic Now". www.ethnicnow.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 21 January 2018. Retrieved 2018-01-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Precious Awards 2008". preciousawards.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 21 January 2018. Retrieved 2018-01-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. preciousonline (2008-12-02), Precious Awards 2008 | Nike Folayan | Mott Macdonald UK | Winner :: Inspiring Leader within the Workplace, retrieved 2018-01-20 
  10. "About Us - Association For BME Engineers (AFBE-UK)". afbe.org.uk. Archived from the original on 2019-11-02. Retrieved 2018-01-20. 
  11. "STEM Careers for All? Diversity In Engineering | Higher Education Academy". www.heacademy.ac.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20. 
  12. "4 volunteers we want to thank - The Science Council" (in en-GB). The Science Council. 2016-04-20. http://sciencecouncil.org/4-volunteers-we-want-to-thank/. 
  13. "Trustees | etrust". www.etrust.org.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20. 
  14. "Association Established To Give Black and Minority Ethnic People Access to Opportunities in STEM Celebrates 10th Anniversary in London" (in en-GB). Ariatu Public Relations. Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121125734/http://www.ariatupublicrelations.com/news/afbeanniversarygala. 
  15. "#9PercentIsNotEnough Conference - IET Events". events.theiet.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20. 
  16. "About Us - Association For BME Engineers (AFBE-UK)". afbe.org.uk. Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20. 
  17. "AFBE-UK Scotland | AFBE-UK Scotland". www.afbescotland.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20. 
  18. "Vince Cable to speak on Engineering Infrastructure in the UK". PRLog. Retrieved 2018-01-20. 
  19. AFBE UK (2016-08-01), AFBE-UK's Transition in London, retrieved 2018-01-20 
  20. Tideway. "Transition - Tideway helps redress the balance of our industry workforce - Tideway | Reconnecting London with the River Thames" (in en). Tideway. Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121184238/https://www.tideway.london/news/media-centre/transition-tideway-helps-redress-the-balance-of-our-industry-workforce/.