Nike Peller
Ìrísí
Nike Peller jẹ́ òṣèré èdè yorùbá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà àtí oní ìrújú orí ìtàgé.[1][2] Ó jẹ́ ọmọ olóògbé Professor Peller, Nike jẹ́ olóyéYeye Agbasaga ti ìlú Erin Osun tí ó jẹ́ ní ọdún 2010.[3]
Àwọn eré tí ó ti ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Aye Lu
- Adun
- Eni Owo
- Kiniun Alhaji
- Àtànpàkò Otún
- Sekere
- Ayé Ajekú
- Eko O'tobi
- Fila Daddy
- Tomisin
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Asifat, Tade (9 June 2014). "NIKE PELLER EXCLUSIVE: ‘It’s true some of my colleagues are scared of me’ + I look up to God for good children and long life". Ecomium Weekly. http://encomium.ng/nike-peller-exclusive-its-true-some-of-my-colleagues-are-scared-of-me-i-look-up-to-god-for-good-children-and-long-life/. Retrieved 5 February 2016.
- ↑ Adenike, Orenuga (13 May 2014). "Nike Peller follows father’s footsteps, dumps acting for magic [PHOTOS"]. Daily Post Nigeria. http://www.dailypost.ng/2014/05/13/nike-peller-follows-fathers-footsteps-dumps-acting-magic-photos/. Retrieved 5 February 2016.
- ↑ Nathan Nathaniel, Ekpo (24 August 2014). "Magic Earns Former Actress, Nike Peller 5-year Contract". Nigeria Films. http://www.nigeriafilms.com/news/28650/30/magic-earns-former-actress-nike-peller-5-year-cont.html. Retrieved 5 February 2016.