Nikki Giovanni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Nikki Giovanni
Nikki Giovanni speaking at Emory University 2008.jpg
Nikki Giovanni un soro ni Yunifasiti Emory, 2008
Ọjọ́ ìbíOṣù Kẹfà 7, 1943 (1943-06-07) (ọmọ ọdún 76)
Knoxville, Tennessee
Iṣẹ́Olukowe, ako-ewi, alakitiyan, olukowe
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerika
Ìgbà1960s–doni
Website
nikki-giovanni.com

Yolande Cornelia "Nikki" Giovanni, Jr.[1][2] (ibi June 7, 1943) je ako-ewi, olukowe, alawiso, alakitiyan, ati oluko ara Amerika. Ikan ninu awon akoewi to gbajumojulo lagbaye,[2] ninu awon ise re ni awon iwe ewi, awo-orin ewi, ati awon ayoka orisirisi ti won da lori eya, oro awujo ati iwe omode. O ti gba opolopo ebun, ninu won ni Ebun Eso Langston Hughes, Ebun Eniyan NAACP. Won ti yan fun Ebun Grammy, fun awo-orin re The Nikki Giovanni Poetry Collection.[2]


\

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nikki Giovanni", Biography.com.
  2. 2.0 2.1 2.2 Jane M. Barstow, Yolanda Williams Page (eds), "Nikki Giovanni", Encyclopedia of African American Women Writers (Greenwood Publishing Group, 2007), p. 213.