Nnamdi Chimdi Ibekwe
Ìrísí
Nnamdi Chimdi Ibekwe (ojoibi 1972) je oloselu ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà to n sin gẹ́gẹ́ bi ọmọ ile ìgbìmọ̀ asòfin ipinlẹ 8th Abia ti o nsoju agbegbe Bende North labẹ ẹgbẹ́ òsèlú People's Democratic Party (PDP). [1]
Ibekwe n ṣiṣẹ lọwọlọwọ gẹgẹbi Alaga igbimọ Ile-igbimọ lori Isuna ni Ile Igbimọ Asofin Ìpínlẹ̀ Abia. [2] [3]